ARTIKEL SEINDONESIA

Abass Adekunle Adigun

Abass Adekunle Adigun jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìpínlè Oyo. A bí i ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kẹfà ọdún 1970.
Click to read more »

Abass Adigun

Àdàkọ:DMCÀdàkọ:Merge partner Abass Adigun Agboworin je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi Aṣoju ti o n sójú Ibadan North-East / Ibadan South-east ti Ìpínlẹ̀ Ọyọ ni Ile-igbimọ Aṣofin Agba kẹwàá.
Click to read more »

Abayomi Abolaji

Abayomi Abolaji jẹ olukọni ati alábòójútó ọmọ Naijiria lati Ìpínlẹ̀ Eko, Nigeria . Won bi ni ọjọ kọkàndínlógún osu kejìlá ọdún 1964 si Ọgbẹni Olowookere ati Iyaafin Nimat Abolaji.
Click to read more »

Abdeen Abdul

Abdeen Temitope Abdul (tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1995) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ ilẹ̀ Ireland tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù agbábọ́ọ̀lù àárín gbùngbùn fún ẹgbẹ́ ìdíje Deltas asiwaju Indonesia .
Click to read more »

Abdelhak Achik

Abdelhak Achik (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá, osù kẹta ọdun 1959) jẹ́ afẹ̀ṣẹ́jà órilẹ̀-èdè Morocco ìgbà kan rí. Afẹ̀sẹ́jà náà gba àmì ọlá ti idẹ ní olympic tí summer tó wáyé ní Seoul.
Click to read more »

Abdulkareem Adisa

Abdulkareem Adisa (1949 - 25 February 2005) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Click to read more »

Abdullahi Adamu

Abdullahi Adamu listen ⓘ (a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù keje ọdún Ẹgbẹ̀rún kan, ẹgbẹ̀rin ati ọgọ́rùn-ún, ọgọ́ji ati ẹ̀fà) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa ní Nàìjíríà láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1999 sí ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún Ẹgbàá-dún-ó-dèje. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àti alága orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ ti ẹgbẹ́ òṣèlú…
Click to read more »

Abdulsalami Abubakar

Abdulsalami Abubakar (ojoibi June 13, 1942) je omo ologun ara ile Naijiria ati Olori ijoba ile Naijiria lati ojo 9 osu 6, 1998 titi di ojo 29, osu 5, 1999 leyin igba ti Sani Abacha ku.
Click to read more »

Abeer Abdelrahman

Abeer Abdelrahman Khalil Mahmoud ( ti a bi ni ọjọ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 1992) agbẹru ìwúwo ara Egipti. A bi ni Alexandria, Egipti.
Click to read more »

Abiola Adegboyega

Abiola Adegboyega je olukowe omo ile Naijiria.
Click to read more »

Abiola Aderibigbe

Abiola Oluwaseun Adeola Aderibigbe jẹ agbẹjọ́rò, alakada ati oludamọran agbayeara to wa lati ilu Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan ati Nàìjíríà. O jẹ agbẹjọ́rò ti o ni oye meji ni Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ati Wélsì ati Írẹ́lándì.
Click to read more »

Abímbólá Adelakun

Abímbọ́lá Adélakùn Abímbọ́lá Àdùnní Adélakùn ( ọjọ́ ìbí 15 September[ọdún?]) Ó jẹ́ ọ̀nkọ̀wé Nàìjíríà. Ìgbésí ayé A bíi ní ìlú Ìbàdàn, SouthWest Nàìjírià, Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Ibadan, níbití ó tí jáde pẹlú bachelor's degree àti Master of Arts degree in communication and language arts.Ó jáde pẹlú Ph.D. nínú ijó and eré orí ìtàgé ní University of Texas, Austin.[1] Ó ṣiṣé pẹlú The Punch newspaper ní ìlú Èkó, Nàìjírià, gẹ́gẹ́bí…
Click to read more »

Adam Abdulahi

Adam Abdulahi je olukowe omo ile Naijiria.
Click to read more »

Addis Ababa

Addis Ababa jẹ́ olú-ìlú Ethiopia, ó sì tún jẹ́ ìpínlẹ̀ àgbègbè Oromia Pẹ̀lú ìṣirò olùgbé tó tó 2,739,551 gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn Odún 2007, ó jẹ́ ìlú tó tóbi jù lọ ní orílẹ̀-èdè náà àti èyí kejìlá tó tóbi jù lọ ní Áfríkà. Ní gíga 2,355 mítà (7,726 ẹsẹ̀ bàtà), ó jẹ́ olú-ìlú kẹrin tó ga jù lọ ní ayé àti èyí tó ga jù lọ ní Áfríkà.
Click to read more »

Adebayo Adedeji

Adebayo Adedeji (1930-2018) ni a bini oṣù Kejìlá ni Ìjẹ̀bú-Òde, o jẹ amòye ọrọ̀-ajé (Economist) ati akademi ọmọ órilẹ èdè Nàìjíríà. Arakunrin naa jẹKọmiṣọna ti ijọba apapọ órilẹ ede Nàìjíríà lori Ìdàgbàsókè ọrọ̀-ajé ati atúnṣe lati ọdun 1971 dè 1975.
Click to read more »

Adebayo Adefarati

Adebáyò Adéfaratì (February 14, 1931 – March 29 2007) je oloselu ara orile-ede Naijiria ati Gómínà Ìpínlẹ̀ Òndó tele. Adefarati kú ní ojokandinlogbòn osù kéta odún 2007.
Click to read more »

Adedeji Adeleke

Adedeji Tajudeen Adeleke ti a bi ni ojo kefa, osu keta, odun 1957 je olori ile-iwe giga ti orile-ede Naijiria ati aare ile-iwe Adeleke University. Adeleke tún ni oga agba ti Pacific Holdings Limited.
Click to read more »

Adegoke Adelabu

Gbàdàmọ́sí Adégòkè Adélabú tí a bí ní ọjọ́ Kẹta osù Kẹsàn an ọdún 1915 ní ìlú Ìbàdàn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ olóṣèlú àti Mínísítà tẹ́lẹ̀ ohun àlùmọ́nì ati ìgbáyé-gbádùn fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láàrín osù Kínní ọdún 1955 sí oṣù Kínní ọdún 1956, tí ó sì padà di olórí alátakò ní ilé ìgbìmọ̀ọ̀ aṣòfin ní ẹkún ìjọba Ìwọ̀ Oòrùn nígbà ayé rẹ̀. Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí akitiyan ati ipa malegbagbe tí…
Click to read more »

Ademola Adeleke

Ademola Nurudeen Jackson Adeleke ( (Listen ⓘ ) ; tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún ẹgbẹ̀rẹ́gbẹ̀rùn-ún mẹ́rìndínlógún àti àádọ́rin) jẹ́ olóṣèlú àti oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí gómìnà ìpínlẹ̀ Osun láti ọdún ọdún ẹgbẹ̀rún méjì àti ogún méjì. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú fún agbègbè ìgbìmọ̀ aṣòfin Osun-West láti ọdún ẹgbẹ̀rún méjì àti…
Click to read more »

Ademola Adesina

Adéṣínà Adémọ́lá, tí a tún mọ̀ sí Demmy, jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ àti Sabi tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ B Series tí ó ń pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn fún àwọn oníṣòwò ní ilẹ̀ Áfíríkà.
Click to read more »

Aderemi Adegbite

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Aderemi Adeoye

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Aderemi Adesoji

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Adetokunbo Ademola

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Adetunwase Adenle

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Adewale Ademoyega

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Adeyinka Abideen Aderinto

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Adeyinka Adebayo

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Adémọ́lá Adébise

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »

Jimoh Adebowale Adesoye Adetona

Klik untuk melihat detail artikel ini.
Click to read more »
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • »
  • Last

Digital Literacy

PL AR DE EN ES FR IT ARZ NL JA PT CEB SV UK VI WAR ZH RU AF AST AZ BG BN BE CA CS CY DA ET EL EO EU FA GL KO HI HR ID HE KA LA LV LT HU MK MS MIN NO NN CE UZ KK RO SIMPLE SK SL SR SH FI TA TT TH TG TR UR HY MY ACE ALS AM AN BAN BJN BA BS BR CV NV FO FY GA GD GU HA IO IG ILO IA IE OS IS JV KN HT KU KY LB LI MG ML MR MN NE OC OR AS PA PS QU SA SCO SQ SI SD SU SW TL TE VEC VO WA YI YO ZU

Copyright © 2025 ARTIKEL SEINDONESIA All Rights Reserved